1 Sámúẹ́lì 18:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jónátanì bá Dáfídì dá májẹ̀mú nítorí tí ó fẹ́ràn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ara rẹ̀.

1 Sámúẹ́lì 18

1 Sámúẹ́lì 18:1-8