1 Sámúẹ́lì 18:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ọjọ́ náà Ṣọ́ọ̀lù pa Dáfídì mọ́ sí ọ̀dọ̀ rẹ̀ kò sì jẹ́ kí ó padà sí ilé baba rẹ̀ mọ́.

1 Sámúẹ́lì 18

1 Sámúẹ́lì 18:1-8