1 Sámúẹ́lì 18:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jónátanì sì bọ́ aṣọ ìgúnwà, ó sì fi fun Dáfídì pẹ̀lú aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀ rẹ̀ àti pẹ̀lú idà rẹ̀, ọrun rẹ̀ àti àmùrè rẹ̀.

1 Sámúẹ́lì 18

1 Sámúẹ́lì 18:1-5