1 Ọba 6:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Apá kérúbù kìn-ní-ní sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn ún ní gíga, àti apá kérúbù kejì ìgbọ̀nwọ́ márùn ún; ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá láti ṣóńṣó apá kan dé ṣóńṣó apá kejì.

1 Ọba 6

1 Ọba 6:15-33