1 Ọba 6:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní inú-ibi-mímọ́ jùlọ ni ó fi igi ólífì ṣe kérúbù méjì, ọ̀kọ̀ọ̀kan jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá ní gíga.

1 Ọba 6

1 Ọba 6:18-24