1 Ọba 6:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá sì ni kérúbù kejì pẹ̀lú, nítorí kérúbù méjèèje jọ ara wọn ní ìwọ̀n ní títóbi àti títẹ̀wọ̀n bákan náà.

1 Ọba 6

1 Ọba 6:21-30