1 Kọ́ríńtì 12:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé gbogbo ènìyàn ló lè wonisàn bí? Rárá. Ǹjẹ́ gbogbo wa ni Olọ́run fún lẹ̀bùn láti le sọ̀rọ̀ ní èdè tí a kò ì tí ì gbọ́ rí bí? Ṣé ẹnikẹ́ni ló lè túmọ̀ èdè tí wọ̀n sọ tí kò sì yé àwọn ènìyàn bí?

1 Kọ́ríńtì 12

1 Kọ́ríńtì 12:24-31