1 Kọ́ríńtì 12:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n, ẹ máa fi ìtara sàfẹ́rí ẹ̀bùn ti ó tóbi jù.Ṣíbẹ̀ èmi o fi ọ̀nà kan tí ó tayọ rékọjá hàn yín.

1 Kọ́ríńtì 12

1 Kọ́ríńtì 12:30-31