1 Kọ́ríńtì 12:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ gbogbo ènìyàn ni ó jẹ́ àpósítélì bi? Tàbí gbogbo ènìyàn ni wòlíì bí? Ṣe gbogbo ènìyàn ní olùkọ́ni? Ṣé gbogbo ènìyàn ló ní agbára láti ṣe iṣẹ́ ìyanu bí?

1 Kọ́ríńtì 12

1 Kọ́ríńtì 12:22-31