1 Kíróníkà 29:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ti ohun tí ó ṣẹlẹ̀ nígbà ìjọba ọba Dáfídì, láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin, a kọ wọ́n sínú ìwe ìrántí ti Sámúẹ́lì aríran, ìwé ìrántí ti Nátanì wòlíì àti ìwé ìrántí ti Gádì aríran,

1 Kíróníkà 29

1 Kíróníkà 29:26-30