1 Kíróníkà 29:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun sì darúgbó, ó sì kú ikú rere, ó gbádùn ẹ̀mí gígùn, ọlá àti ọrọ̀. Sólómónì ọmọ Rẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò Rẹ̀

1 Kíróníkà 29

1 Kíróníkà 29:23-30