1 Kíróníkà 29:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

lápapọ̀, pẹ̀lú gbogbo ìjọba àti agbára Rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ìgbà tí ó kọjá lórí Rẹ̀, àti lórí Ísírẹ́lì, àti lórí gbogbo àwọn ìjọba gbogbo ilẹ̀ náà.

1 Kíróníkà 29

1 Kíróníkà 29:22-30