1 Kíróníkà 27:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóábù ọmọ Ṣérúyà bẹ̀rẹ̀ sí ní kàwọ́n, ṣùgbọ́n kò parí kíkà wọ́n nítorí, ìbínú dé sórí àwọn Ísírẹ́lì nipaṣẹ̀ kíka iye àti iye náà, a kò kọọ́ sínu ìwé ìtàn ayé ti ọba Dáfídì.

1 Kíróníkà 27

1 Kíróníkà 27:23-28