1 Kíróníkà 27:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áṣímáfétì ọmọ Ádíélì wà ní ìdí ilé ìṣúra ti ọba. Jónátanì ọmọ Úṣíà wà ní ìdí ilé ìṣúra ní iwájú agbègbè nínú àwọn ìlú, àwọn ìlètò àti àwọn ilé ìṣọ́.

1 Kíróníkà 27

1 Kíróníkà 27:20-34