1 Kíróníkà 27:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì kò kọ iye àwọn ọkùnrin náà ní ogún ọdún sẹ́yìn tàbí dín nítori Olúwa ti ṣe ìlerí lati ṣe Ísírẹ́lì gẹ́gẹ́ bí iye ìràwọ̀ ojú ọ̀run.

1 Kíróníkà 27

1 Kíróníkà 27:15-30