1 Kíróníkà 19:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ará Ámónì jáde wá, wọ́n sì dá isẹ́ ogun ní àbáwọlé sí ìlú ńlá wọn, nígbà tí àwọn ọba tí ó wá, fún rara wọn wà ni orílẹ̀ èdè tí ó sí sílẹ̀.

1 Kíróníkà 19

1 Kíróníkà 19:4-11