1 Kíróníkà 19:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní gbígbọ́ eléyìí, Dáfídì rán Jóábù jáde pẹ̀lú gbogbo àwọn ọmọ ogun ọkùnrin tí ó le jà.

1 Kíróníkà 19

1 Kíróníkà 19:1-11