1 Kíróníkà 19:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóábù ri wí pé àwọn ìlà ogun wà níwájú àti ẹ̀yìn òun; Bẹ́ẹ̀ ni ọmọ ogun tí ó dára ní Ísírẹ́lì, o sì tẹ́ ogun wọn sí àwọn ará Ṣíríà.

1 Kíróníkà 19

1 Kíróníkà 19:1-11