1 Kíróníkà 19:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó fi ìyókù àwọn ọkùnrin náà sí abẹ́ àkóso Ábíṣáì arákùrin Rẹ̀, a sì tẹ́ wọn kí wọn dojúkọ àwọn ará Ámónì.

1 Kíróníkà 19

1 Kíróníkà 19:4-17