1 Kíróníkà 19:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóábù wí pé Tí àwọn ará Ṣíríà bá le jù fún mi, nígbà náà, ìwọ ni kí o gbà mí; Ṣùgbọ́n tí àwọn ará Ámónì bá le jù fún ọ, Nígbà náà èmi yóò gbà ọ́.

1 Kíróníkà 19

1 Kíróníkà 19:10-15