1 Kíróníkà 14:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì mọ Ísírẹ̀lì àti pé Olúwa ti fi òun ṣe ọba lórí Ísírẹ́lì àti pé Ìjọba Rẹ̀ ga jùlọ nítorí ti àwon ènìyàn Rẹ̀.

1 Kíróníkà 14

1 Kíróníkà 14:1-8