1 Kíróníkà 14:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní Jérúsálẹ́mù Dáfídì mú ọ̀pọ̀ ìyàwó ó sì di bàbá àwọn ọmọ ọkùnrin púpọ̀ àti ọmọbìnrin.

1 Kíróníkà 14

1 Kíróníkà 14:1-10