1 Kíróníkà 14:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsìn yìí Hírámù àti ọba Tírè rán oníṣẹ́ sí Dáfídì, àti pẹ̀lú igi kédérì pẹ̀lú àwọn ọ̀mọ̀lé àti gbẹ́nàgbẹ́nà láti kọ́ ààfin fún un.

1 Kíróníkà 14

1 Kíróníkà 14:1-6