1 Kíróníkà 14:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni Dáfídì ṣe ohun tí Ọlọ́run ti pa láṣẹ fún wọn, wọ́n sì kọ lu àwọn ọmọ ogun Fílístínì láti gbogbo ọ̀nà Gíbíónì lọ sí Géṣérì.

1 Kíróníkà 14

1 Kíróníkà 14:12-17