1 Kíróníkà 14:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ó bá sì ṣe, tí ẹ̀yin bá ti gbọ́ ìró yíyan ẹsẹ̀ ní orí òkè igi Bálísámù, ẹ jáde fún ogun, nítorí èyí yóò fi hàn pé Ọlọ́run ti jáde níwájú rẹ láti kọlu àwọn ọmọ ogun Fílístínì.

1 Kíróníkà 14

1 Kíróníkà 14:5-17