1 Kíróníkà 14:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni òkìkí Dáfídì tàn ká gbogbo ilẹ̀ káàkiri, Olúwa sì mú kí gbogbo orílẹ̀ èdè bẹ̀rù Rẹ̀.

1 Kíróníkà 14

1 Kíróníkà 14:8-17