1 Kíróníkà 13:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àpótí ẹ̀rí Olúwa sì wà lọ́dọ̀ àwon ará ilé Obedi-Édómù ní ilé Rẹ̀ fún oṣù mẹ́ta, Olúwa sì bùkún agbo ilé àti gbogbo ohun tí ó ní.

1 Kíróníkà 13

1 Kíróníkà 13:11-14