O. Daf 45:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃li Ọba yio fẹ ẹwà rẹ gidigidi: nitori on li Oluwa rẹ; ki iwọ ki o si ma sìn i.

O. Daf 45

O. Daf 45:5-12