O. Daf 124:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. IBA máṣe pe Oluwa ti o ti wà fun wa, ki Israeli ki o ma wi nisisiyi;

2. Iba máṣe pe Oluwa ti o ti wà fun wa, nigbati awọn enia duro si wa:

O. Daf 124