O. Daf 123:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọkàn wa kún pupọ̀-pupọ̀ fun ẹ̀gan awọn onirera, ati fun ẹ̀gan awọn agberaga.

O. Daf 123

O. Daf 123:2-4