Eks 29:46 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn o si mọ̀ pe emi li OLUWA Ọlọrun wọn, ti o mú wọn lati ilẹ Egipti jade wá, ki emi ki o le ma gbé ãrin wọn: emi li OLUWA Ọlọrun wọn.

Eks 29

Eks 29:45-46