Eks 29:45-46 Yorùbá Bibeli (YCE) Emi o si ma gbé ãrin awọn ọmọ Israeli, emi o si ma ṣe Ọlọrun wọn. Nwọn o si mọ̀ pe emi li OLUWA