Orin Dafidi 68:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí èéfín tií pòórá,bẹ́ẹ̀ ni kí wọn parẹ́;bí ìda tií yọ́ níwájú iná,bẹ́ẹ̀ ni kí àwọn eniyan burúkú parun níwájú Ọlọrun.

Orin Dafidi 68

Orin Dafidi 68:1-5