Matiu 6:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí gbogbo nǹkan wọnyi ni àwọn abọ̀rìṣà ń lépa. Nítorí Baba yín tí ń bẹ ní ọ̀run mọ̀ pé ẹ nílò gbogbo wọn.

Matiu 6

Matiu 6:30-34