Matiu 6:31 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, ẹ má ṣe àníyàn pé kí ni ẹ óo jẹ? Tabi, kí ni ẹ óo mu? Tabi kí ni ẹ óo fi bora?

Matiu 6

Matiu 6:21-33