Kọrinti Kinni 12:30-31 BIBELI MIMỌ (BM)

30. Kì í ṣe gbogbo yín ni ẹ ní ẹ̀bùn kí á ṣe ìwòsàn. Bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe gbogbo yín ni ẹ lè sọ èdè àjèjì. Àbí gbogbo yín ni ẹ lè túmọ̀ àwọn èdè àjèjì?

31. Ẹ máa fi ìtara lépa àwọn ẹ̀bùn tí ó ga jùlọ.Ṣugbọn n óo fi ọ̀nà kan tí ó dára jùlọ hàn yín.

Kọrinti Kinni 12