Kọrinti Kinni 11:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ebi bá ń pa ẹnikẹ́ni, kí ó jẹun kí ó tó kúrò ní ilé, kí ìpéjọpọ̀ yín má baà jẹ́ ìdálẹ́bi fun yín. Nígbà tí mo bá dé, n óo ṣe ètò nípa àwọn nǹkan tí ó kù.

Kọrinti Kinni 11

Kọrinti Kinni 11:28-34