Joṣua 23:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé, OLUWA ti lé àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n tóbi tí wọ́n sì ní agbára kúrò níwájú yín, kò sì tíì sí ẹni tí ó lè ṣẹgun yín títí di òní.

Joṣua 23

Joṣua 23:1-10