Joṣua 23:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn OLUWA Ọlọrun yín ni kí ẹ súnmọ́ gẹ́gẹ́ bí ẹ ti ṣe títí di òní.

Joṣua 23

Joṣua 23:1-14