Jeremaya 48:10 BIBELI MIMỌ (BM)

(Ègún ń bẹ lórí ẹni tí ó bá ń fi ìmẹ́lẹ́ ṣe iṣẹ́ OLUWA;ègún sì ń bẹ lórí ẹni tí ó bá sì kọ̀, tí kò máa fi idà rẹ̀ pa eniyan.)

Jeremaya 48

Jeremaya 48:8-16