Jeremaya 40:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sì ti ṣe bí ó ti pinnu nítorí pé ẹ dẹ́ṣẹ̀ sí i, ẹ kò sì fetí sí ohùn rẹ̀, nítorí náà ni ibi ṣe dé ba yín.

Jeremaya 40

Jeremaya 40:1-7