Jeremaya 40:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nebusaradani, olórí àwọn ẹ̀ṣọ́ ọba Babiloni, sọ fún Jeremaya pé, “OLUWA Ọlọrun rẹ ti pinnu láti ṣe ilẹ̀ yìí ní ibi;

Jeremaya 40

Jeremaya 40:1-3