Ẹsita 5:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn gbogbo nǹkan wọnyi kò lè tẹ́ mi lọ́rùn, bí mo bá ń rí Modekai, Juu, tí ó ń jókòó ní ẹnu ọ̀nà ààfin ọba.”

Ẹsita 5

Ẹsita 5:12-14