Aisaya 53:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n tẹ́ ẹ sí ibojì, pẹlu àwọn eniyan burúkú,wọ́n sì sin ín pẹlu ọlọ́rọ̀,bẹ́ẹ̀ ni kò ṣe ẹnikẹ́ni níbi,kò sì sọ̀rọ̀ ẹ̀tàn.

Aisaya 53

Aisaya 53:5-12