Aisaya 53:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n mú un lọ tipátipá,lẹ́yìn tí wọ́n ti dá a lẹ́jọ́,ta ni ninu ìran rẹ̀ tí ó ṣe akiyesi péwọ́n ti pa á run lórí ilẹ̀ alààyè,ati pé nítorí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn eniyan mi, ni wọ́n ṣe nà án?

Aisaya 53

Aisaya 53:4-10