Aisaya 32:18-20 BIBELI MIMỌ (BM)

18. Àwọn eniyan mi yóo máa gbé pẹlu alaafia,ní ibùgbé tí ó ní ààbò ati ibi ìsinmi tí ó ní ìbàlẹ̀ àyà.

19. Yìnyín yóo bọ́, yóo bo gbogbo ilẹ̀,a óo sì pa ìlú náà run patapata.

20. Ayọ̀ ẹ̀yin tí ẹ̀ ń fúnrúgbìn sí etí odò yóo pọ̀,ẹ̀yin tí ẹ ní mààlúù ati kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tí ń jẹ káàkiri.

Aisaya 32