Aisaya 32:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ayọ̀ ẹ̀yin tí ẹ̀ ń fúnrúgbìn sí etí odò yóo pọ̀,ẹ̀yin tí ẹ ní mààlúù ati kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tí ń jẹ káàkiri.

Aisaya 32

Aisaya 32:16-20