Sekaráyà 13:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì ṣe, ni gbogbo ilẹ̀,” ni Olúwa wí,“a ó gé apá méjì nínú rẹ̀ kúrò yóò sì kú;ṣùgbọ́n apá kẹta yóò kù nínú rẹ̀.

Sekaráyà 13

Sekaráyà 13:5-9