Sekaráyà 13:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Díde, ìwọ idà, sí olùṣọ́-àgùntàn mi,àti sí ẹni tí í ṣe ẹnìkejì mi,”ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí:“Kọlu Olùṣọ́-àgùntàn,àwọn àgùntàn a sì túká:èmi o sì yí ọwọ́ mi sí àwọn kékèké.

Sekaráyà 13

Sekaráyà 13:5-9