Sekaráyà 12:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìdílé Léfì lọ́tọ̀, àti àwọn aya wọn lọ́tọ̀; ìdílé Ṣimei lọ́tọ̀, àti àwọn aya wọn lọ́tọ̀.

Sekaráyà 12

Sekaráyà 12:11-14